Joṣua 10:7 BM

7 Joṣua bá lọ láti Giligali, òun ati àwọn ọmọ ogun rẹ̀, pẹlu gbogbo àwọn tí wọ́n jẹ́ akikanju ati akọni.

Ka pipe ipin Joṣua 10

Wo Joṣua 10:7 ni o tọ