Joṣua 13:25 BM

25 Ilẹ̀ tiwọn ni Jaseri ati gbogbo ìlú Gileadi, ati ìdajì ilẹ̀ àwọn ará Amoni, títí dé Aroeri tí ó wà ní ìlà oòrùn Raba;

Ka pipe ipin Joṣua 13

Wo Joṣua 13:25 ni o tọ