Joṣua 13:28 BM

28 Àwọn ìlú ńláńlá ati ìlú kéékèèké tí ó wà ninu ilẹ̀ yìí jẹ́ ìpín ẹ̀yà Gadi gẹ́gẹ́ bí iye ìdílé wọn.

Ka pipe ipin Joṣua 13

Wo Joṣua 13:28 ni o tọ