Joṣua 14:11 BM

11 bí agbára mi ṣe rí nígbà tí Mose rán wa jáde láti lọ ṣe amí, bẹ́ẹ̀ náà ni ó wà títí di òní olónìí, mo tún lágbára láti jagun ati láti wọlé ati láti jáde.

Ka pipe ipin Joṣua 14

Wo Joṣua 14:11 ni o tọ