Joṣua 15:63 BM

63 Ṣugbọn àwọn eniyan Juda kò lè lé àwọn Jebusi tí wọn ń gbé inú ilẹ̀ Jerusalẹmu jáde. Àwọn Jebusi yìí sì tún wà láàrin àwọn eniyan Juda ní Jerusalẹmu títí di òní olónìí.

Ka pipe ipin Joṣua 15

Wo Joṣua 15:63 ni o tọ