Joṣua 18:1 BM

1 Lẹ́yìn tí àwọn ọmọ Israẹli ti ṣẹgun ilẹ̀ náà, gbogbo wọn péjọ sí Ṣilo, wọ́n sì pa àgọ́ àjọ níbẹ̀.

Ka pipe ipin Joṣua 18

Wo Joṣua 18:1 ni o tọ