Joṣua 19:1 BM

1 Ilẹ̀ keji tí wọ́n ṣẹ́ gègé lé lórí bọ́ sí ọwọ́ ẹ̀yà Simeoni, ilẹ̀ tiwọn bọ́ sí ààrin ìpín ti ẹ̀yà Juda.

Ka pipe ipin Joṣua 19

Wo Joṣua 19:1 ni o tọ