Joṣua 19:12 BM

12 Láti Saridi, ààlà ilẹ̀ náà lọ sí òdìkejì, ní ìhà ìlà oòrùn, títí dé ààlà Kisiloti Tabori, láti ibẹ̀, ó lọ sí Daberati títí lọ sí Jafia;

Ka pipe ipin Joṣua 19

Wo Joṣua 19:12 ni o tọ