Joṣua 19:15 BM

15 Ara àwọn ìlú tí ó wà níbẹ̀ ni, Kata, Nahalali, Ṣimironi, Idala, ati Bẹtilẹhẹmu, gbogbo ìlú ati ìletò wọn jẹ́ mejila.

Ka pipe ipin Joṣua 19

Wo Joṣua 19:15 ni o tọ