Joṣua 19:49 BM

49 Nígbà tí àwọn ọmọ Israẹli pín gbogbo agbègbè tí ó wà ninu ilẹ̀ náà ní ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan tán, wọ́n pín ilẹ̀ fún Joṣua ọmọ Nuni pẹlu.

Ka pipe ipin Joṣua 19

Wo Joṣua 19:49 ni o tọ