Joṣua 19:9 BM

9 Apá kan ninu ilẹ̀ ẹ̀yà Juda jẹ́ ìpín ti ẹ̀yà Simeoni. Ìpín ti ẹ̀yà Juda tóbi jù fún wọn, nítorí náà ni ẹ̀yà Simeoni ṣe mú ninu tiwọn.

Ka pipe ipin Joṣua 19

Wo Joṣua 19:9 ni o tọ