Joṣua 2:23 BM

23 Àwọn ọkunrin meji náà sọ̀kalẹ̀ láti orí òkè, wọ́n lọ bá Joṣua, ọmọ Nuni, wọ́n bá sọ gbogbo ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí wọn fún un.

Ka pipe ipin Joṣua 2

Wo Joṣua 2:23 ni o tọ