20 Láti inú ilẹ̀ ẹ̀yà Efuraimu ni wọ́n ti gba ìlú fún àwọn ọmọ Kohati yòókù, tí wọ́n jẹ́ ẹ̀yà Lefi.
Ka pipe ipin Joṣua 21
Wo Joṣua 21:20 ni o tọ