Joṣua 21:25 BM

25 Ninu ilẹ̀ ìdajì ẹ̀yà Manase, wọ́n fún wọn ní àwọn ìlú wọnyi pẹlu àwọn pápá ìdaran tí ó wà ní àyíká wọn: Taanaki, ati Gati Rimoni, wọ́n jẹ́ ìlú meji.

Ka pipe ipin Joṣua 21

Wo Joṣua 21:25 ni o tọ