Joṣua 21:40 BM

40 Ìlú mejila ni wọ́n fún àwọn ìdílé yòókù ninu ẹ̀yà Lefi tí à ń pè ní Merari gẹ́gẹ́ bí iye ìdílé wọn.

Ka pipe ipin Joṣua 21

Wo Joṣua 21:40 ni o tọ