Joṣua 21:42 BM

42 Olukuluku àwọn ìlú yìí ní pápá ìdaran tí ó yí i ká, bẹ́ẹ̀ náà ni gbogbo àwọn ìlú yòókù.

Ka pipe ipin Joṣua 21

Wo Joṣua 21:42 ni o tọ