45 Ninu gbogbo ìlérí dáradára tí OLUWA ṣe fún ilé Israẹli kò sí èyí tí kò mú ṣẹ; gbogbo wọn patapata ni ó mú ṣẹ.
Ka pipe ipin Joṣua 21
Wo Joṣua 21:45 ni o tọ