Joṣua 22:12 BM

12 Nigba tí àwọn ọmọ Israẹli gbọ́ èyí, gbogbo wọ́n bá péjọ sí Ṣilo láti lọ bá wọn jagun.

Ka pipe ipin Joṣua 22

Wo Joṣua 22:12 ni o tọ