Joṣua 22:2 BM

2 ó wí fún wọn pé, “Gbogbo ohun tí Mose, iranṣẹ OLUWA pa láṣẹ fun yín ni ẹ ti ṣe; ẹ sì ti ṣe gbogbo ohun tí èmi náà pa láṣẹ fun yín.

Ka pipe ipin Joṣua 22

Wo Joṣua 22:2 ni o tọ