Joṣua 23:3 BM

3 ẹ̀yin náà ti rí ohun tí OLUWA Ọlọrun yín ti ṣe sí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè wọnyi nítorí yín, ati pé OLUWA Ọlọrun yín ni ó jà fun yín.

Ka pipe ipin Joṣua 23

Wo Joṣua 23:3 ni o tọ