Joṣua 24:10 BM

10 Ṣugbọn n kò fetísí ọ̀rọ̀ Balaamu; nítorí náà ìre ni ó sú fun yín, mo sì gbà yín kúrò lọ́wọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Joṣua 24

Wo Joṣua 24:10 ni o tọ