Joṣua 24:3 BM

3 Láti òdìkejì odò náà ni mo ti mú Abrahamu baba yín, mo sìn ín la gbogbo ilẹ̀ Kenaani já; mo sì sọ arọmọdọmọ rẹ̀ di pupọ. Mo fún un ní Isaaki;

Ka pipe ipin Joṣua 24

Wo Joṣua 24:3 ni o tọ