30 Wọ́n bá sin ín sórí ilẹ̀ rẹ̀ ní Timnati Sera, tí ó wà ní agbègbè olókè Efuraimu, ní apá ìhà àríwá Gaaṣi.
Ka pipe ipin Joṣua 24
Wo Joṣua 24:30 ni o tọ