Joṣua 6:11 BM

11 Bẹ́ẹ̀ ni ó mú kí wọn gbé Àpótí Majẹmu OLUWA yí ìlú náà po lẹ́ẹ̀kan, nígbà tí ó di alẹ́, wọ́n pada sinu àgọ́ wọn, wọ́n sì sùn sibẹ.

Ka pipe ipin Joṣua 6

Wo Joṣua 6:11 ni o tọ