Joṣua 6:24 BM

24 Wọ́n dáná sun ìlú náà ati gbogbo nǹkan tí ó wà ninu rẹ̀, àfi fadaka ati wúrà, ati àwọn ohun èlò idẹ, ati ti irin, ni wọ́n kó lọ sinu ilé ìṣúra OLUWA.

Ka pipe ipin Joṣua 6

Wo Joṣua 6:24 ni o tọ