Joṣua 6:26 BM

26 Joṣua bá gégùn-ún nígbà náà pé,“Ẹni ìfibú OLUWA ni ẹnikẹ́ni tí ó bá dìde láti tún ìlú Jẹriko kọ́.Àkọ́bí ẹni tí ó bá fi ìpìlẹ̀ rẹ̀ lélẹ̀ yóo kú,àbíkẹ́yìn rẹ̀ yóo kú nígbà tí ó bá gbé ìlẹ̀kùn ibodè rẹ̀ ró.”

Ka pipe ipin Joṣua 6

Wo Joṣua 6:26 ni o tọ