Joṣua 6:7 BM

7 Ó sọ fún àwọn eniyan náà pé, “Ẹ máa tẹ̀síwájú, ẹ rìn yípo ìlú náà kí àwọn ọmọ ogun ṣáájú Àpótí Majẹmu OLUWA.”

Ka pipe ipin Joṣua 6

Wo Joṣua 6:7 ni o tọ