Joṣua 7:22 BM

22 Joṣua bá ranṣẹ, wọ́n sáré lọ wo inú àgọ́ rẹ̀, wọ́n bá àwọn nǹkan náà ní ibi tí ó bò wọ́n mọ́, ó fi fadaka tẹ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Joṣua 7

Wo Joṣua 7:22 ni o tọ