Joṣua 8:12 BM

12 Joṣua ṣa nǹkan bí ẹgbẹẹdọgbọn (5,000) ọmọ ogun, ó fi wọ́n pamọ́ sí ààrin Bẹtẹli ati Ai ní apá ìwọ̀ oòrùn Ai.

Ka pipe ipin Joṣua 8

Wo Joṣua 8:12 ni o tọ