Joṣua 8:19 BM

19 Gbogbo àwọn tí wọn farapamọ́ bá yára dìde ní ibi tí wọ́n wà. Bí Joṣua ti na ọwọ́ rẹ̀, wọ́n sáré wọ inú ìlú náà, wọ́n gbà á, wọ́n sì yára sọ iná sí i.

Ka pipe ipin Joṣua 8

Wo Joṣua 8:19 ni o tọ