Joṣua 8:27 BM

27 Àfi ẹran ọ̀sìn ati dúkìá ìlú náà ni àwọn ọmọ Israẹli kó ní ìkógun gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún Joṣua.

Ka pipe ipin Joṣua 8

Wo Joṣua 8:27 ni o tọ