Joṣua 8:8 BM

8 Gbàrà tí ẹ bá ti gba ìlú náà tán, ẹ ti iná bọ̀ ọ́, kí ẹ sì ṣe bí àṣẹ OLUWA. Ó jẹ́ àṣẹ tí mo pa fun yín.”

Ka pipe ipin Joṣua 8

Wo Joṣua 8:8 ni o tọ