Joṣua 9:19 BM

19 Ṣugbọn gbogbo àwọn àgbààgbà dá ìjọ eniyan náà lóhùn pé, “A ti búra fún wọn ní orúkọ OLUWA Ọlọrun Israẹli, a kò sì gbọdọ̀ fọwọ́ kàn wọ́n mọ́.

Ka pipe ipin Joṣua 9

Wo Joṣua 9:19 ni o tọ