Samuẹli Keji 21:8 BM

8 Ṣugbọn ó mú Arimoni ati Mẹfiboṣẹti àwọn ọmọkunrin mejeeji tí Risipa, ọmọ Aya, bí fún Saulu; ó sì tún mú àwọn ọmọ marun-un tí Merabu, ọmọbinrin Saulu, bí fún Adirieli ọmọ Basilai ará Mehola.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 21

Wo Samuẹli Keji 21:8 ni o tọ