Samuẹli Kinni 1:16 BM

16 Má rò pé ọ̀kan ninu àwọn oníranù obinrin ni mí. Ninu ìbànújẹ́ ńlá ati àníyàn ni mò ń gbadura yìí.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 1

Wo Samuẹli Kinni 1:16 ni o tọ