Samuẹli Kinni 10:18 BM

18 Ó sọ fún wọn pé, “OLUWA Ọlọrun Israẹli ní, ‘Mo kó yín jáde wá láti Ijipti, mo gbà yín kalẹ̀ lọ́wọ́ àwọn ará Ijipti, ati gbogbo àwọn eniyan yòókù tí wọn ń ni yín lára.’

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 10

Wo Samuẹli Kinni 10:18 ni o tọ