Samuẹli Kinni 10:6 BM

6 Nígbà náà, ẹ̀mí OLUWA yóo bà lé ọ, o óo sì darapọ̀ mọ́ wọn, o óo sì máa sọ àsọtẹ́lẹ̀, o óo sì yàtọ̀ patapata sí bí o ti wà tẹ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 10

Wo Samuẹli Kinni 10:6 ni o tọ