Samuẹli Kinni 12:20 BM

20 Samuẹli dá wọn lóhùn pé, “Ẹ má bẹ̀rù, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ohun tí ẹ ṣe burú, sibẹsibẹ ẹ má ṣe yipada kúrò lọ́dọ̀ OLUWA, ṣugbọn ẹ máa sìn ín pẹlu gbogbo ọkàn yín.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 12

Wo Samuẹli Kinni 12:20 ni o tọ