20 Nígbà tí àwọn ọmọ Israẹli bá fẹ́ pọ́n ohun ìtúlẹ̀ wọn ati ọkọ́ ati àáké ati dòjé, wọ́n níláti lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn ará Filistia.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 13
Wo Samuẹli Kinni 13:20 ni o tọ