9 Nítorí náà, Saulu ní kí wọ́n gbé ẹbọ sísun ati ẹbọ alaafia wá fún òun, ó sì rú ẹbọ.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 13
Wo Samuẹli Kinni 13:9 ni o tọ