Samuẹli Kinni 14:10 BM

10 Ṣugbọn bí wọ́n bá ní kí á máa bọ̀ lọ́dọ̀ àwọn, a óo tọ̀ wọ́n lọ. Èyí ni yóo jẹ́ àmì fún wa, pé OLUWA ti fún wa ní ìṣẹ́gun lórí wọn.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 14

Wo Samuẹli Kinni 14:10 ni o tọ