Samuẹli Kinni 14:19 BM

19 Bí Saulu ti ń bá alufaa náà sọ̀rọ̀ lọ́wọ́, ìdàrúdàpọ̀ tí ó wà ninu àgọ́ àwọn ọmọ ogun Filistini ń pọ̀ sí i. Nítorí náà, Saulu wí fún un pé kí ó dáwọ́ dúró.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 14

Wo Samuẹli Kinni 14:19 ni o tọ