Samuẹli Kinni 14:23 BM

23 Bẹ́ẹ̀ ni OLUWA ṣe ṣẹgun fún àwọn ọmọ Israẹli ní ọjọ́ náà, wọ́n sì ja ogun náà kọjá Betafeni.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 14

Wo Samuẹli Kinni 14:23 ni o tọ