Samuẹli Kinni 14:7 BM

7 Ọdọmọkunrin náà dá a lóhùn pé, “Ohunkohun tí ọkàn rẹ bá fẹ́ ni kí o ṣe. Mo wà lẹ́yìn rẹ, bí ọkàn rẹ ti rí ni tèmi náà rí.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 14

Wo Samuẹli Kinni 14:7 ni o tọ