11 “Ó dùn mí pé mo fi Saulu jọba. Ó ti yipada kúrò lẹ́yìn mi, kò sì pa òfin mi mọ́.” Inú bí Samuẹli, ó sì gbadura sí OLUWA ní gbogbo òru ọjọ́ náà.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 15
Wo Samuẹli Kinni 15:11 ni o tọ