18 Ó sì rán ọ jáde pẹlu àṣẹ pé kí o pa gbogbo àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀, ará Amaleki run. Ó ní kí o gbógun tì wọ́n títí o óo fi pa wọ́n run patapata.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 15
Wo Samuẹli Kinni 15:18 ni o tọ