2 OLUWA àwọn ọmọ ogun ní, ‘N óo jẹ àwọn ará Amaleki níyà nítorí pé wọ́n gbógun ti àwọn ọmọ Israẹli, nígbà tí wọ́n ń bọ̀ láti Ijipti.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 15
Wo Samuẹli Kinni 15:2 ni o tọ