20 Saulu dá a lóhùn pé, “Mo ti pa òfin OLUWA mọ́, mo jáde lọ bí o ti wí fún mi pé kí n jáde lọ, mo mú Agagi ọba pada bọ̀, mo sì pa gbogbo àwọn ará Amaleki run.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 15
Wo Samuẹli Kinni 15:20 ni o tọ