34 Lẹ́yìn náà, Samuẹli pada lọ sí Rama, Saulu ọba sì pada lọ sí ilé rẹ̀ ní Gibea ti Saulu.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 15
Wo Samuẹli Kinni 15:34 ni o tọ