Samuẹli Kinni 16:10 BM

10 Jese mú kí àwọn ọmọ rẹ̀ mejeeje kọjá níwájú Samuẹli. Ṣugbọn Samuẹli wí fún un pé, OLUWA kò yan ọ̀kankan ninu wọn.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 16

Wo Samuẹli Kinni 16:10 ni o tọ